ÈYÍ GAN-AN NI Ẹ̀SÌN ISLĀM
Change LanguageMenu
Bíbá
ara rẹ́ ẹ̀sìn àti làákàyè
Apákan nínú àwọn ènìyàn máa ń lérò pé dájúdájú ẹ̀sìn tako làákàyè, ó sì tako ìlànà ìmọ̀;
Al-Qur’ān alápọ̀n-ọ́nlé
jẹ́ iṣẹ́-ìyanu gbére fún ẹ̀sìn Islām
Kín ni Al-Qur’ān, èyí tó jẹ́ wí pé ọ̀pọ̀ ìgbà ni ó máa ń gbawájú gẹ́gẹ́ bíi ìwé tó tà jùlọ,
Ẹ̀sìn Islām
kó gbogbo agbegbe ìgbésí-ayé ènìyàn sínú
Àwọn àgbélẹ̀rọ ìròrí kan ka ènìyàn sí ọ̀gá pátápátá fún ilé-ayé yìí, èyí tó le máa darí rẹ̀ ní ìbámu sí àǹfààní rẹ̀ àti àwọn ohun tó fẹ́, láìsí ẹnìkankan tí yóò ṣe ìṣirò iṣẹ̀ rẹ̀ tàbí olùṣọ́. Kódà kí èyí fa bíba àwọn abala kan nínú ilé-ayé yìí jẹ́, tàbí yóò kó ìparun bá

Àwọn ìjọsìn nínú

ẹ̀sìn Islām, kín ni pàápàá wọn?

Ṣé Ọlọ́hun bùkáátà sí ìjọsìn wa?Ọlọ́hun Ọba Abiyì, tí Ó ga, kò bùkáátà sí ìjọsìn wa àti àwọn iṣẹ́ wa.  Ọlà àti yíyege, nínú ẹ̀sìn Islām, kò mọ lórí àwọn ètò ìjọsìn, àwọn ìrísí àti àwọn fífi owó dá ọlá. Ṣùgbọ́n pẹ̀lú bí jíjẹ́

prayer
  • Àjọṣepọ̀ tó wà láàrin òfin àdámọ́ àti òfin ìdájọ́ ẹ̀sìn Ọlọ́hun
  • Kò sí jíjẹ́ alagbà nínú ẹ̀sìn Islām
  • Ṣé ìlànà àrà ọ̀tọ̀ kan ń bẹ fún wíwọnú ẹ̀sìn Islām bí?

Àdẹ́dàá kan
ṣoṣo.. Ẹni tí à ń jọ́sìn fún kan ṣoṣo

  • Ọlọ́hun sọ Al-Qur’ān kalẹ̀ fún un:
  • Ìgbẹ̀yìn àwọn Ànábì àti àwọn Ìránṣẹ́ Ọlọ́hun: 
  • default
  • 2. Ìṣẹ̀mí àti ìdàgbàsókè rẹ̀,3. Gbígbé e dìde ní Òjíṣẹ́
  • 4. Ìbẹ̀rẹ̀ pípèpè rẹ̀,5. Fífi ìlú Makkah sílẹ̀ rẹ̀ 
  • 6. Bí ó ti tan ẹ̀sìn Islām ká,7. Ikú rẹ̀

Tani Ìránṣẹ́
tí Ọlọ́hun fi ẹ̀sìn Islām rán:

  • Àwọn Mùsùlùmí darí ìlú Íńdíà, fún ohun tó fẹ́ẹ̀ tó ẹgbẹ̀rún ọdún, 80% àwọn tó ń gbé ìlú Íńdíà nígbà náà kì í ṣe Mùsùlùmí
  • Àwọn Mùsùlùmí darí ìlú Andalus fún ọrúndún mẹ́jọ
  • Àwọn Mùsùlùmí darí ìlú Miṣr fún ọgọ́rùn-ún mẹ́rìnlà, wọ́n sí bá àwọn ìran Aqbāt ṣọ́ ipò wọn

Ṣé ó jẹ
àwọn ènìyàn nípa láti wọnú ẹ̀sìn Islām bí?